NAME OF HERBS & SPICES IN YORUBA.
1. Tiger nut – Ofio
2. Onion – Alubọsa
3. Ginger – Atalẹ
4. Bell pepper – Tataṣe
5. Garlic – Ayù
6. Kola nut – Obi
7. Cinnamon – Oriira
8. Walnut – Awùsá/Àsálà
9. Spring onion – Alubọsa Elewe
10. Bitter Kola – Orogbo
11. Basil – Efinrin
12. Bitterleaf – Ewuro
13. Indigo plant – Èlú (Aro)
14. Shea butter – Òrí
15. Chili pepper/Bonnet – Ata rodo
16. Alligator pepper – Atare
17. Grape – Eso Àjàrà
18. Water letuce – Ojú oró
19. Nutmeg – Aríwó
20. Dates – Labidun
21. Bitter melon – Ejirin Wewe
22. Eggplant – Igba/Ikan
23. Cayenne pepper – Ṣọmbọ
24. Tumeric – Ajo (Atalẹ pupa)
25. Marijuana – Igbó
26. Corn silk – Irukere Agbado
27. Lemon – Ijaganyin
28. Jute – Ewedu
29. Tamarind – Awin
30. Pumpkin – Elégédé
31. Lime – Osan wewe
32. Bamboo – Oparun
33. Moringa – Ewelẹ
34. Watermelon – Ibara
35. Wild lettuce – Ẹfọ Yanrin
36. Aloe vera – Eti Erin
37. Milkweed – Bomubomu
38. Roselle Hibiscus – Iṣapa
39. Cucumber – Apálá
40. Camwood – Osùn
41. Plum -Ìgọ
42. Hog plum – Ìyeyè
43. Almond – Ofio omu
44. Miracle berry – Agbayun
45. Black pepper – Iyere
46. Lotus plant- Oṣibata
47. Bush mango – Oro
48. Fig – Ọ̀pọ̀tọ́ (Eeya)
49. Siam weed – Ewe Akintola
50. Raffia palm – Ògùrọ
51. Earth chestnut – Botuje
52. Sugar cane – Ireke
53. Bush mango (seed) – Àpòn
54. Waterleaf – Ẹfọ Gbure
55. Ackee – Iṣin
56. Bambara nut – Ẹpa roro/Orubu
57. Spinach – Ẹfọ Tẹtẹ